.lv

.lv ni amioro orile-ede top-level domain (ccTLD) lori Internet fun Latvia.

14 July

13 July | 14 July | 15 July

2015

Odun 2015

8 May

7 May | 8 May | 9 May

Fránsì

Fránsì (pípè /ˈfræns/ ( listen) franss tabi /ˈfrɑːns/ frahns; French pronunciation : [fʁɑ̃s]), fun ibise gege bi Ile Faranse Olominira (Faranse: République française, pípè: [ʁepyblik fʁɑ̃sɛz]), je orile-ede ni apa iwoorun Europe, to ni opolopo agbegbe ati erekusu ni oke okun ti won wa ni awon orile miran. Fransi je orile-ede onisokan olominira ti aare die ti bi o se n sise wa ninu Ipolongo awon eto Eniyan ati ti Arailu.

Fáwẹ̀lì Yorùbá

Fáwẹ̀lì Yorùbá

ISBN

International Standard Book Number (ISBN) jẹ́ àìlẹ́gbẹ́ oùnka tí wọ́n fi ń dá ìwé mọ̀.

ISO 3166

ISO 3166 je apa meta opagun amioro, fun agbegbe lati se amioro fun awon orile-ede, awon agbegbe to ba le won ati ipin apa won, ti Àgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págun tesiwejade. Oruko re gangan ni Awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won.

ISO 8601

ISO 8601 je opagun kariaye.

Itálíà

Itálíà (Ítálì: Italia; Gẹ̀ẹ́sì: Italy) tabi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Itálíà je orile-ede ni orile Europe.

Parisi

Parisi (Faranse: Paris) jẹ́ olúìlú orílẹ̀-èdè Fránsì àti ìlú tó tobijulọ nibẹ. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 105.40 km² pẹ̀lú olùgbélú 2,220,445 ní ìkànìyàn ọdún 2014.

Portable Document Format

Portable Document Format je opagun kariaye.

Wiki

Wiki

Wikimedia

Wikimedia Foundation, Inc.

Wikipedia

Wikipedia jé isé owó òpòlopò àwon ènìyàn kâkiríayé láti se ìwé ìmò tó jé òfé ni òpòlopò èdè ni òrí Internet ti Wikimedia Foundation n se onigbowo.

Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkà

Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkà (I.A.A) tabi Àwọn Ìpínlẹ̀ Asokan (I.A tabi ni Geesi: USA tabi US), tàbí Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tabi Amerika ni soki, jẹ́ orílé-èdè ijoba àpapò olominira pèlú iwe-ofin ibagbepo tí ó ni adota ipinle, agbegbe ijoba-apapo kan ati agbegbe merinla, ti o wa ni Ariwa Amerika. Ilẹ̀ re fe lati Òkun Pasifiki ni apa iwoorun de Òkun Atlántíkì ni apa ilaorun. O ni bode pelu ile Kanada ni apa ariwa ati pelu Meksiko ni apa guusu. Ipinle Alaska wa ni ariwaiwoorun, pelu Kanada ni ilaorun re ati Rosia ni iwoorun niwaju Bering Strait. Ipinle Hawaii je agbajo erekusu ni arin Pasifiki. Orile-ede awon Ipinle Aparapo tun ni opolopo agbegbe ni Karibeani ati Pasifiki.

Èdè Gẹ̀ẹ́sì

Èdè Gẹ̀ẹ́sì

Èdè Yorùbá

Èdè Yorùbá Ni èdè tí ó ṣàkójọ pọ̀ gbogbo káàrọ̀ o-ò-jíire, níapá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà, tí a bá wo èdè Yorùbá, àwọn onímọ̀ pín èdè náà sábẹ́ ẹ̀yà Kwa nínú ẹbí èdè Niger-Congo. Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ẹ̀yà Kwa yìí ló wọ́pọ̀ jùlọ ní sísọ, ní ìwọ̀ oòrùn aláwọ̀ dúdú fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ọdún. Àwọn onímọ̀ èdè kan tilẹ̀ ti fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ pé láti orírun kan náà ni àwọn èdè bí Yorùbá, Kru, Banle, Twi, Ga, Ewe, Fon, Edo, Nupe, Igbo, Idoma, Efik àti Ijaw ti bẹ̀rẹ̀ sí yapa gẹ́gẹ́ bi èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tó dúró láti bí ẹgbẹ̀rún mẹ́ta ọ̀dún sẹ́yìn.

Ṣàngó

Ṣàngó Olukoso, Oko Oya.

Ìkàwé ní èdè míràn