ISBN

International Standard Book Number (ISBN) jẹ́ àìlẹ́gbẹ́ oùnka tí wọ́n fi ń dá ìwé mọ̀.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

  1. US ISBN Agency. "Bowker.com – Products". Commerce.bowker.com. Retrieved 2015-06-11.
  2. Gregory, Daniel. "ISBN". PrintRS. Retrieved 2015-06-11.
Abkhazia

Abkhazia (Àdàkọ:Lang-ab Apsny, IPA /apʰsˈnɨ/; Àdàkọ:Lang-ka Apkhazeti; Rọ́síà: Абхазия Abkhaziya) is a disputed territory on the eastern coast of the Black Sea and the south-western flank of the Caucasus.

Abkhazia considers itself an independent state, called the Republic of Abkhazia or Apsny. This status is recognised by Russia, Nicaragua, Venezuela, Nauru, Tuvalu and Vanuatu and also by the partially recognised states of South Ossetia, Transnistria and Nagorno-Karabakh.

Ahmose 2k

Amasis II (bakanna bi Ahmose II) je Farao ni ile Egipti.

Amenemhat 1k

Amenemhat I je Farao ni ile Egipti.

Bèbè Ìlàòrùn

Bèbè Ìlàòrùn tabi West Banki (Lárúbáwá: الضفة الغربية‎, aḍ-Ḍiffä l-Ġarbīyä) (Hébérù: הגדה המערבית‎, HaGadah HaMa'aravit)

Djoser

Netjerikhet tabi Djoser (Turin King List "Dsr-it"; Manetho "Tosarthros")

Djoser je Farao ni ile Egipti.

Fluorínì

Fluorínì ( /ˈflʊəriːn/, /ˈflʊərɪn/, tabi /ˈflɔrʔ/) je apilese kemika pelu nomba atomu 9, to je sisoju pelu ami-idamo F. Fluorin da ide eyokan po mo ara re to ba wa bi apilese, eyi unfa owon F2 alatomumeji. F2 (fluorin) je efuufu pipon brown rodonrondon to undarapomora kiakia, onimojele. Fluorin alapilese ni o je eyi toun darapomora bi kemika ati alodiafinagbe julo larin gbogbo awon apilese. Fun apere, yio tete "jo" awon haidrokarbon nina ni igbonasi inuyara, ni iyato si bi awon haidrokarbon se un gbanaje pelu oksijin, to gbodo ni afikun okun pelu isana. Nitorie, fluorin owon lewu gidi, be ju awon halojin yiowu bi efuufu klorin onimajele lo.

Georgia

Georgia je orile-ede ni agbegbe Kafkasusi ni Euroasia.

Georgios Kountouriotis

Georgios Kountouriotis (Gíríkì: Γεώργιος Κουντουριώτης) (1782 - 1858) jẹ́ alákoso àgbà orílẹ̀-èdè Griisi tẹ́lẹ́. Saronic island of Hydra to an Arvanite Greek family.

Ilẹ̀ Ọbalúayé Rómù

Ilẹ̀ Ọbalúayé Rómù (Roman Empire) tabi Ile Romu ni igba eyin toloselu to sele ni Romu Atijo, to je ti ijoba oseluenikan to ni agbegbe kakiri Europe ati yipo agbegbe Mediterranean. Oro yi bere si je lilo lati juwe ile ijoba Romu nigba ati leyin obaluaye ibe akoko Augustus.

Khafra

Khafra (Greek, Χεφρήν; Chephren) — also Khafre je Farao ni ile Egipti.

Khufu

Khufu (ni Griiki bi Χέοψ, Cheops, pípè /ˈhɛɒps/; bi Manetho se so, Σοῦφις, Suphis) je Farao ni ile Egipti.

Kroatíà

Kroatíà tabi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kroatíà je orile-ede ni Guusuilaoorun Europe.

Ksenon

Ksenon (pípè /ˈzɛnɒn/; ZEE-non) je apilese kemika to ni ami-idamo Xe. Nomba atomu re je 54. O je Efuufu alade to wuwo, lai lawo tabi ni oorun, ksenoni wa ni ojuorun ni iye tasere.Ksenọ̀nù?

Merikare

Merikare jẹ́ Fáráò ni Ẹ́gíptì Ayéijọ́un.

Nepherites 1k

Oba Nepherites I, tabi Nefaarud I je Farao ni ile Egipti.

Thutmose 3k

Thutmose III

Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì

Tábìlì ìdásìkò àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo. Bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele, eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry Ararussia Dimitri Mandeleev ni odun 1869. Mandeleev fe tabili yi lati s'afihan ("igba") isele bi a se n da awon apilese mo. Atunse ti bo si iyasile tabili yi, be ni o si ti fe si bi a ba se n seawari awon apilese tuntun be sini a ti se iko apere elero (theoretical model) tuntun la ti se alaye iwuwa egbo.Tabili igba ti je pataki nisinyi ninu imo eko Khemistry, nipa lati pin si owoowo, la si ona to mogbon wa ati lati safiwe awon orisirisi iru iwa egbo. Be na sini tabili yi n je lilo ninu eko Fisiki, Biology, imoero ati Ileise ero. Tabili ise (standard) isinyi ni 117 apilese ti a le fihan gege bi January 27, 2008 (nigbati apilese 118 ti je imudipo (synthesized) apilese 117 ko ti je be).

Ẹ̀fúùfù abíire

Àwọn Ẹ̀fúùfù abíire únjẹ́ lílò nínú kẹ́místrì láti fi ṣe ìsètò àwọn apilẹ̀ṣẹ̀ kẹ́míkà.

Àwọn èdè míràn

This page is based on a Wikipedia article written by authors (here).
Text is available under the CC BY-SA 3.0 license; additional terms may apply.
Images, videos and audio are available under their respective licenses.