22 May

Ọjọ́ 22 Oṣù Kàrún tabi 22 May jẹ́ ọjọ́ 142nd nínú ọdún (143rd ní ọdún tódọ́gba) nínú kàlẹ́ndà Gregory. Ó ṣẹ́ ku ọjọ́ 223 títí di òpin ọdún.

Oṣù Kàrún
Àìkú Ajé Ìsẹ́gun Ọjọ́rú Ọjọ́bọ̀ Ẹtì Àbámẹ́ta
1 2 3 4
5 6 7 8 9 10 11
12 13 14 15 16 17 18
19 20 21 22 23 24 25
26 27 28 29 30 31
 
2019
21 May

20 May | 21 May | 22 May

Ọjọ́ 21 Oṣù Kàrún tabi 21 May jẹ́ ọjọ́ 141st nínú ọdún (142nd ní ọdún tódọ́gba) nínú kàlẹ́ndà Gregory. Ó ṣẹ́ ku ọjọ́ 224 títí di òpin ọdún.

23 May

22 May | 23 May | 24 May

Ọjọ́ 23 Oṣù Kàrún tabi 23 May jẹ́ ọjọ́ 143rd nínú ọdún (144th ní ọdún tódọ́gba) nínú kàlẹ́ndà Gregory. Ó ṣẹ́ ku ọjọ́ 222 títí di òpin ọdún.

Ali Abdullah Saleh

Ali Abdullah Saleh (Lárúbáwá: علي عبدالله صالح‎; ojoibi 21 March 1946 tabi 1942) lo je was the first Aare akoko Orileolominira Yemen. Saleh teletele je Aare Orileolominira Arabu Yemen (Ariwa Yemen) lati 1978 titi de 1990, nigbato bo sipo bi alaga Igbimo Aare Orileolominira Yemen (unified Yemen). Ohun ni aare Yemen to pejulo lori aga, nigba to wa nibe lati 1978.

Constantine 1k

Caesar Flavius Valerius Aurelius Constantinus Augustus (27 February c. 272 – 22 May 337) je obaluaye ni Ileobaluaye Romu tele.

Dragon (ọkọ̀-òfurufú)

The Dragon is a reusable spacecraft developed by SpaceX, a private space transportation company based in Hawthorne, California. During its uncrewed maiden flight in December 2010, Dragon became the first commercially-built and operated spacecraft to be recovered successfully from orbit. On 25 May 2012, an uncrewed variant of Dragon became the first commercial spacecraft to successfully rendezvous with the International Space Station (ISS).

Etta James

Etta James (oruko abiso Jamesetta Hawkins, Oṣù Kínní 25, 1938 - Oṣù Kínní 20, 2012) je akorin blues, soul, R&B, rock & roll, gospel ati jazz ara Amerika. Eni to bere ise orin kiko larin ewadun 1950, o gbajumo pelu orin bi "Dance With Me, Henry", "At Last", "Tell Mama", ati "I'd Rather Go Blind", awon eyi to ko fun ra re. O koju orisirisi isoro, larin eyi ti se lilo ogun oloro, ko to tun gbe awo rin miran jade ni opin ewadun 1980 pelu awo orin "The seven year Itch".Won gba pe o se japo orin rhythm and blues ati rock and roll, be sini o gba Ebun Grammy ni emefa ati Ebun Orin Blues ni eme 17. Won fun ni eye fifi si Rock and Roll Hall of Fame ni 1993, si Blues Hall of Fame ni 2001, ati si Grammy Hall of Fame ni 1999 ati 2000. Iwe iroyin olosoosu Rolling Stone fun ni ipo 22 ninu atojo awon akorin 100 to se pataki julo lailai ati ipo 62 ninu atojo awon onisona 100 to se pataki julo.

Kurmanbek Bakiyev

Kurmanbek Saliyevich Bakiyev (Kyrgyz: Курманбек Сали уулу Бакиев (Kurmanbek Sali Uulu Bakiev), èdè Rọ́síà: Курманбек Салиевич Бакиев; ojoibi 1 August 1949) je oloselu to je second Aare keji ile Kyrgyzstan lati 2005 de 2010.

Manmohan Singh

Manmohan Singh (Punjabi: ਮਨਮੋਹਨ ਸਿੰਘ, born 26 September 1932) ni Alakoso Agba ile India lati odun 2004.

National Youth Service Corps

Àjọ eletò Agùnbánirọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà tí a mọ̀ sí (NYSC) The National Youth Service Corps jẹ́ ètò tí ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà gbé kàlẹ̀ fún àwọn ọ̀dọ́ langba tí wọ́n ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde ilé ẹ̀kọ́ ńlá ńlá jáàkiri ilẹ̀ Nàìjíríà, léte àti lè jẹ́ kí àwọn ọ̀dọ́ wọ̀yí ó lè mú iṣẹ́ ìdàgbà sókè ilẹ̀ baba wọn ní ọ̀kúnkún dùn. Bì ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, kìíbfipá múni láti dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ kgun. Àmọ́, ní ọdún 1973 ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà fòté lé wípé kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè ilé ẹ̀kọ́ Fásitì àti Pólì ilẹ̀ Nàìjíríà ó ma kópa nínú iṣẹ̀ agùnbánirọ̀ ní ikẹ̀ Nàìjíríà fún ọdún kan péré. Èyí bi a mọ̀ sí ọdún ìsinlẹ̀ baba ẹni. Ọ̀gbẹ́ni Ahmadu Ali ló kọ́kọ́ jẹ́ adarí àgbà àkọ́kọ́ fún àjọ náà títí di ọdún 1975. Tí èni tó eà níbẹ̀ lásìkò yí jẹ́ Director-General ìyẹn ọ̀gágun Brig. Gen. Sule Zakari Kazaure.

Àkójọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Túrkì

Àkójọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Túrkì ti orile-ede Túrkì.

İsmet İnönü

Mustafa İsmet İnönü (Àdàkọ:IPA-tr; 24 September 1884 – 25 December 1973) je Aare ati Alakoso Agba orile-ede Turki tele.

Àwọn èdè míràn

This page is based on a Wikipedia article written by authors (here).
Text is available under the CC BY-SA 3.0 license; additional terms may apply.
Images, videos and audio are available under their respective licenses.