1785

| Ọ̀rúndún 17k | Ọ̀rúndún 18k | 19k |
◄◄ | | 1781 | 1782 | 1783 | 1784 | 1785 | 1786 | 1787 | 1788 | 1789 | | ►►


Ọdún 1785

1781

Ọdún 1781

1782

Ọdún 1782

1783

Ọdún 1783

1784

Ọdún 1784

1785 Wurm

1785 Wurm jẹ́ plánẹ́tì kékeré ní ibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì.

1786

Ọdún 1786

1787

Ọdún 1787

1788

Ọdún 1788

1789

Ọdún 1789

Aaron Burr

Aaron Burr, Jr. (February 6, 1756 – September 14, 1836) je oloselu ara Amerika, to kopa ninu Ogun Ijidide Amerika, ati arinkerindo. O di Igbakeji Aare iketa (1801–1805), labe Aare Thomas Jefferson, ohun ni igbakeji aare akoko ti ko di aare rara.

Agustín Gamarra

Agustín Gamarra jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Perú tẹ́lẹ̀.

Benjamin Franklin

Benjamin Franklin (January 17, 1706 [O.S. January 6, 1705] – April 17, 1790) je oloselu ati ikan ninu awon Baba Oludasile orile-ede Amerika.

Samuel Adams

Wọ́n bí Adams ní ọdún 1722. Ó kú ní 1803. Olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Àmẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wa. Boston ni wọ́n ti bí i. Láti nǹkan bíi 1765 ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí (no taxation without representation). Ó gbé ‘Boston tea-party’ ga. Ní 1776, ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira (declaration of independent).

Springbok

springbok jẹ́ alábọ́dé ẹtu tí wọ́n ń rí ní gúúsù áfríkà àti gúúsù-wọ̀orùn áfríkà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Antidorcas, Jẹ́mánì onímọ̀ ẹranko Eberhard August Wilhelm von Zimmermann ló kọ́kọ́ ṣe àpèjuwe ọmọ ẹbí Bovidae yìí ní ọdún 1780. Ẹ̀yà méta ẹranko yìí tí di mímọ̀. Ẹtu èyí tẹ́ẹ́rẹ́ tẹ́sẹrẹ̀ gùn, springbok gùn tó 71 sí 86 cm (28 to 34 in) ní ìwọ̀n èjìká àti ìwúwosí láti 27 sí 42 kg (60 sí 93 lb). Akọ àti abo rẹ̀ ní ìho méjì tí ó yípo sẹ́yìn. Springbok yìí ma ń ní ojú funfun, ìlà dúdú láti ojú dé ẹnu, àwọ̀ pako fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ tí ó pupa díẹ̀ láti apá iwájú dé íbubu ìha ìdí rẹ̀.

Ara rẹ̀ ma ń yá gágá ní àfẹ̀mọ́jú àti àṣàalẹ́, springbok fọ́ọ̀mù àdàlù ìbálòpọ̀. Ní ìgàkan sẹ́yìn, springbok ti aṣálẹ Kalahari àti ti Karoo ma ń kóra wọn kọjá ní igbóẹgàn, lèyí tí à ń pè ní trekbokken.

Thomas Jefferson

Thomas Jefferson (April 13, 1743 – July 4, 1826) je oloselu ara Amerika ati Aare ibe tele.

Àfin Beaumont

Àfin Beaumont , tí wọ́n Henry I kọ́ sí gúúsù ọ̀nà àbáwọlé Oxford ní ọdún 1130 gẹ́gẹ́ bí àfin ọba kí ó lè súnmọ́ ibi tí ọba ti ń rẹra ní Woodstock (nísìn ó jẹ́ ara Àfin Blenheim).

Ẹ̀wádún 1780

Ẹ̀wádún 1780

Àwọn èdè míràn

This page is based on a Wikipedia article written by authors (here).
Text is available under the CC BY-SA 3.0 license; additional terms may apply.
Images, videos and audio are available under their respective licenses.