Àdájọba

Àdájọba tabi Ìdọ́bajẹ (monarchy) je iru ijoba kan nibi ti gbogbo agbara oloselu wa patapata tabi ni oloruko lowo enikan tabi awon eyan kan. Gege bi ohun oloselu, oludajoba ni olori orile-ede, won wa nipo yi titi di igba ti wo ba ku tabi sakuro lori ite, be sini "o je yiyasoto kuro lodo gbogbo awon omo egbe orile-ede miran."[1] Eni toun solori ijoba adajoba ni aunpe ni adobaje tabi oludajoba. Iru ijoba yi lo wopo laye nigba ijoun ati oju dudu.

Lowolowo, awon orile-ede 44 ni won ni oludajoba gege bi awon olori orile-ede, 16 ninu won je Ile Ajoni ti won gba Queen Elizabeth II gege bi olori orile-ede won.

World Monarchies
     Absolute monarchy     Semi-constitutional monarchy     Constitutional monarchy     Commonwealth realms (consitutional monarchies in personal union)     Subnational monarchies (traditional)

Itokasi

  1. "Bouvier, John, and Francis Rawle. Bouvier's Law Dictionary and Concise Encyclopedia. 1914. 2237-2238.
Christos Sartzetakis

Christos Sartzetakis jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Constantine 2k ilẹ̀ Gríìsì

Constantine 2k ilẹ̀ Gríìsì jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

George 2k ilẹ̀ Gríìsì

George 2k ilẹ̀ Gríìsì jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Georgios Zoitakis

Georgios Zoitakis jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Ioannis Alevras

Ioannis Alevras jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Karolos Papoulias

Karolos Papoulias (Gíríkì: Κάρολος Παπούλιας, [ˈkaɾo̞ˌlo̞s paˈpuʎas]; ojoibi June 4, 1929) ni Aare orile-ede Griisi.

Konstantinos Karamanlis

Konstantinos tabi Constantine Karamanlis (Gíríkì: Κωνσταντίνος Καραμανλής) (8 March 1907 - 23 April 1998) je Alakoso Agba ati Aare orile-ede Griisi tele.

Konstantinos Stephanopoulos

Konstantinos Stephanopoulos (Gíríkì: Κωνσταντίνος Στεφανόπουλος, ojoibi August 15, 1926) lo je Aare kefa Igba Oselu Iketa orílẹ̀-èdè Gríìsì.

Konstantinos Tsatsos

Konstantinos Tsatsos jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Michail Stasinopoulos

Michail Stasinopoulos jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Pavlos Kountouriotis

Pavlos Kountouriotis (Gíríkì: Παύλος Κουντουριώτης, 9 April 1855 - 22 August 1935) je Griiki Ogagun ojuomi ati akoni ologun ojuomi nigba Awon Ogun Balkan ati Aare ekini ati eketa orile-ede Griisi.

Phaedon Gizikis

Phaedon Gizikis jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Páúlù ilẹ̀ Gríìsì

Páúlù ilẹ̀ Gríìsì jẹ́ Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Theodoros Pangalos (ọ̀gágun)

Theodoros Pangalos (Gíríkì: Θεόδωρος Πάγκαλος) (11 January 1878 – 26 February 1952) jẹ́ Alákóso Àgbà ati Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Àwọn èdè míràn

This page is based on a Wikipedia article written by authors (here).
Text is available under the CC BY-SA 3.0 license; additional terms may apply.
Images, videos and audio are available under their respective licenses.